Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions Atheism - Wikipedia

Atheism

From Wikipedia

Atheism

Asawale, Paul

ASAWALE PAUL

ATHEISM: ÈKÓ ÀÌGBÀNGBÓ PÉ OLÓRUN WÀ.

Àwon Gírúkì (Greeks) ni wón kókó lo òrò yìí- Atheism. Tí abá fo sí wéwé ni wíwò mofólójì rè A + theos = Atheos. “A”- túmò sí “not” ni ède Gèésì, èyí tí a le túmò sí “kò jé” ní èdè Yorùbá, “theos-túmò sí-“god”ní èdè Gèésì, èyí tí á jé “Olorun” ní ède Yorùbá. Tí a bá wá kan án pò á wá jé “atheos” ní Gíríkì, “not god” ní Gèésì, àti “ko je olórun ni ède Yorùbá.

KÍ NI ÀWON ELÉRÒ YÌÍ Ń SO

Àwon elérò yìí kò gbàgbó nínú wíwà olórun (Exstance of God or gods) kankan bóyá ni mú aféfé ohun èlò ken, tàbí nínú èmí. Ní tiwon kò sí Olórun. Àwon elérò yìí ní àwon ní ìmò tàbí èye pé kò sí olórun hàn kò gbà pé Olórun wà. Won ní ìgbàgbó nínú olórun jé ìgba ohun asan gbo.

VOLTAIRE onímo ìjìnlè kan ni ó se agbáterù oye yìí.

ÀWON IYÀN WON:

(1) Wón ko gbogbo ònà ìkàsìn tàbí ònà àtijó ti àwon ènìyàn ti lò láti fi ìdí wíwà Olórun múle. Ara àwon ònà yìí ni a le ri nínú Bíbélì àti kùránì. Àwon mìíràn tilè gbàgbó wí pé Olórun wà nítorí àwon nnkàn tí o ń selè tàbí wà ní àyíká wa tí a kò lè mo yalè won. Wón ní Olórun nìkan ni ìtumò àwon nnkan wòn yìí. Àwon “Atheist” ni iró ni. Èyí kò fi hàn pé Olórun wà.

(2) Ìbèrù ìgbèyìn ayé tí a kò mo ni ó ń bami lérù tí a fi ń gbàgbó lórí ifa omírà jagun lórí àìsàn, ikú, òsì àti beebe lo. Èrò àbámò àti àìní ènòjinlè ni eléyìí.

(3) Gbogbo àwon àbùdá ti a fun àwon ti a pè ní Olorun yìí, a rà wón bo wón lórún nì.

(4) Ò soro láti gbè pe Olórun tí o ní gbogbo agbára tí ó sì mo ohun gbogbo lè jé ki ibi dé bá èdá owó o rè

(5) Láti so pè àdìtú ni àwon nnkan wònyìí fí èrò nípa Olórun hàn gégé bí ohun ti kò sí nínú ayé èdá kò si yé kí á kobiara sí i.

(6) Àwon elérò yìí tàbùkù ìgbògbó Olorun nínú Bíbélì àti kùránì. Wón tako olorun owú àti esan wón.

ÌPÌLÈ ÈRÒ ÈKÓ ÀÌGBÀGBÓ PÉ OLÓRUN WÀ

Ní àpá ìlà oòrùn àgbáyé ni èrò yìí ti kókó Gbile ní pàtó láti orílè èdè “India”. Èrò yìí je jáde láti inú òpòpolò èrò bíi “cationalism, Materialism” “Buddisim àti béèbéè lo. Ogbéni kan ti o se agbáterù rè jù ni ADVAITA VEDANTA ti ilú SHANKARA. Títi di bíi séńtury méjìdìnlógún (18th C.) kò sí eni tí ó gbódò so nípa èrò yìí nínú àwùjo àwon onígbàgbó. Wón gbàgbó pé èrò yìí lè kó bá ìwà omolùà bi ènìyàn àti ìwà ìbán-enígbépò sùgbón àwon elérò mìíràn tí a pè ní DEISM ní ìbámu pèlú onimò ìjìnlè kan –EPICURUS (341-270bc), tún so pé bí àwon Olórun bá tilè alà won kò ní nnkan-kan se pèlú ènìyàn tàbí wíwá rè. Òfun ìle Améríkà, èyí ti THOMAS JEFFERSON so pé o pa ààlà láàrin ìjo (church) àti ìlú ti esè rè mùlè pé kókó jabele ni òrò èsùn, kò gbódò kan ìlú. Bèrè lati (19th Centry) Sentury mókàndínlógún àwon èlèrò yìí ti pò sí bíi:- Perry Bysshe, Tayler Coleridge àti béè béè lo. Wón so pé àtiowódá tàbí àfògbón-hun ní òrò èsùn. Wón ni ò kàn ń gba díè lára ohun rere àti díè lara ohun burúkú owó èdá ni.

Static Wikipedia 2006 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr -
 
ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext -
fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz -
 
ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky -
la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn -
 
na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt -
qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl -
 
ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh -
yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -

Static Wikipedia 2008 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -